1 Sámúẹ́lì 20:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, Jónátánì ní kí Dáfídì tún búra nítorí ìfẹ́ tí ó ní sí i, nítorí pé ó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ó ṣe nífẹ̀ẹ́ ara* rẹ̀.+ 1 Sámúẹ́lì 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ní ti ìlérí tí èmi àti ìwọ jọ ṣe,+ kí Jèhófà wà láàárín wa títí láé.”+
17 Torí náà, Jónátánì ní kí Dáfídì tún búra nítorí ìfẹ́ tí ó ní sí i, nítorí pé ó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ó ṣe nífẹ̀ẹ́ ara* rẹ̀.+