1 Sámúẹ́lì 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìgbà náà ni Dóẹ́gì+ ọmọ Édómù tó ń bójú tó àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù fèsì pé:+ “Mo rí ọmọ Jésè tó wá sí Nóbù lọ́dọ̀ Áhímélékì ọmọ Áhítúbù.+ Sáàmù 52:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Sí olùdarí. Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tí Dóẹ́gì ọmọ Édómù wá, tó sì sọ fún Sọ́ọ̀lù pé Dáfídì wá sí ilé Áhímélékì.+
9 Ìgbà náà ni Dóẹ́gì+ ọmọ Édómù tó ń bójú tó àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù fèsì pé:+ “Mo rí ọmọ Jésè tó wá sí Nóbù lọ́dọ̀ Áhímélékì ọmọ Áhítúbù.+
Sí olùdarí. Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tí Dóẹ́gì ọmọ Édómù wá, tó sì sọ fún Sọ́ọ̀lù pé Dáfídì wá sí ilé Áhímélékì.+