Sáàmù 56:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tí ẹ̀rù ń bà mí,+ mo gbẹ́kẹ̀ lé ọ.+ Sáàmù 56:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wọ́n fara pa mọ́ láti gbéjà kò mí;Wọ́n ń ṣọ́ gbogbo ìrìn ẹsẹ̀ mi,+ Kí wọ́n lè gba ẹ̀mí mi.*+