ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 19:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Torí náà, Jónátánì sọ̀rọ̀ Dáfídì ní rere+ níwájú Sọ́ọ̀lù bàbá rẹ̀. Ó sọ fún un pé: “Kí ọba má ṣàìdáa sí* Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ̀, nítorí kò ṣẹ̀ ọ́, àwọn ohun tó ṣe fún ọ sì ti ṣe ọ́ láǹfààní.

  • 1 Sámúẹ́lì 20:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Àmọ́, Jónátánì sọ fún Sọ́ọ̀lù bàbá rẹ̀ pé: “Kí nìdí tí wọ́n á fi pa á?+ Kí ló ṣe?”

  • 1 Sámúẹ́lì 24:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Bàbá mi, wò ó, etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ tí kò lápá rèé lọ́wọ́ mi; nígbà tí mo gé etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ tí kò lápá, mi ò pa ọ́. Ṣé ìwọ náà rí i, ṣé o sì ti wá mọ̀ báyìí pé mi ò gbèrò láti ṣe ọ́ ní jàǹbá tàbí kí n dìtẹ̀ sí ọ? Mi ò ṣẹ̀ ọ́,+ àmọ́ ńṣe ni ò ń dọdẹ mi kiri láti gba ẹ̀mí* mi.+

  • 1 Sámúẹ́lì 26:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jèhófà ló máa san òdodo àti ìṣòtítọ́ kálukú+ pa dà fún un, torí pé Jèhófà fi ọ́ lé mi lọ́wọ́ lónìí, àmọ́ mi ò fẹ́ gbé ọwọ́ mi sókè sí ẹni àmì òróró Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́