-
1 Sámúẹ́lì 2:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Èèyàn Ọlọ́run kan wá sọ́dọ̀ Élì, ó sì sọ fún un pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Ǹjẹ́ mi ò fara han ilé baba rẹ nígbà tí wọ́n wà ní Íjíbítì, tí wọ́n jẹ́ ẹrú ní ilé Fáráò?+
-
-
1 Sámúẹ́lì 2:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Bí mo ti ń ṣe rere fún Ísírẹ́lì, alátakò ni wàá máa rí nínú ibùgbé mi,+ kò tún ní sí ẹni tó máa dàgbà nínú ilé rẹ mọ́ láé.
-