Sáàmù 52:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Sí olùdarí. Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tí Dóẹ́gì ọmọ Édómù wá, tó sì sọ fún Sọ́ọ̀lù pé Dáfídì wá sí ilé Áhímélékì.+
Sí olùdarí. Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tí Dóẹ́gì ọmọ Édómù wá, tó sì sọ fún Sọ́ọ̀lù pé Dáfídì wá sí ilé Áhímélékì.+