1 Sámúẹ́lì 22:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tó yá, wòlíì Gádì+ sọ fún Dáfídì pé: “Má ṣe gbé ní ibi ààbò mọ́. Lọ sí ilẹ̀ Júdà.”+ Torí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì lọ sí igbó Hérétì.
5 Nígbà tó yá, wòlíì Gádì+ sọ fún Dáfídì pé: “Má ṣe gbé ní ibi ààbò mọ́. Lọ sí ilẹ̀ Júdà.”+ Torí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì lọ sí igbó Hérétì.