1 Sámúẹ́lì 23:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Dáfídì mọ̀ pé* Sọ́ọ̀lù ti jáde lọ láti gba ẹ̀mí* òun nígbà tí Dáfídì ṣì wà ní aginjù Sífù ní Hóréṣì.
15 Dáfídì mọ̀ pé* Sọ́ọ̀lù ti jáde lọ láti gba ẹ̀mí* òun nígbà tí Dáfídì ṣì wà ní aginjù Sífù ní Hóréṣì.