-
1 Sámúẹ́lì 26:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Sọ́ọ̀lù pàgọ́ sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà lórí òkè Hákílà tó dojú kọ Jéṣímónì. Nígbà náà, Dáfídì ń gbé ní aginjù, ó sì gbọ́ pé Sọ́ọ̀lù ti wá òun wá sínú aginjù náà.
-