Sáàmù 54:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí àwọn àjèjì dìde sí mi,Àwọn ìkà ẹ̀dá sì ń wá ẹ̀mí* mi.+ Wọn ò ka Ọlọ́run sí.*+ (Sélà)