1 Sámúẹ́lì 25:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní báyìí, pinnu ohun tí o máa ṣe, torí àjálù máa tó dé bá ọ̀gá wa àti gbogbo ilé rẹ̀,+ aláìníláárí*+ ni, kò sì sí ẹni tó lè bá a sọ̀rọ̀.” 1 Sámúẹ́lì 25:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Dáfídì ti ń sọ pé: “Lásán ni mo ṣọ́ gbogbo nǹkan tí ọ̀gbẹ́ni yìí ní nínú aginjù. Kò sí ìkankan lára gbogbo ohun tó jẹ́ tirẹ̀ tó sọ nù,+ síbẹ̀ ibi ló fi san ire pa dà fún mi.+
17 Ní báyìí, pinnu ohun tí o máa ṣe, torí àjálù máa tó dé bá ọ̀gá wa àti gbogbo ilé rẹ̀,+ aláìníláárí*+ ni, kò sì sí ẹni tó lè bá a sọ̀rọ̀.”
21 Dáfídì ti ń sọ pé: “Lásán ni mo ṣọ́ gbogbo nǹkan tí ọ̀gbẹ́ni yìí ní nínú aginjù. Kò sí ìkankan lára gbogbo ohun tó jẹ́ tirẹ̀ tó sọ nù,+ síbẹ̀ ibi ló fi san ire pa dà fún mi.+