1 Sámúẹ́lì 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nábálì dá àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì lóhùn pé: “Ta ni Dáfídì, ta sì ni ọmọ Jésè? Lóde òní, ọ̀pọ̀ àwọn ìránṣẹ́ ló ń sá kúrò lọ́dọ̀ ọ̀gá wọn.+
10 Nábálì dá àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì lóhùn pé: “Ta ni Dáfídì, ta sì ni ọmọ Jésè? Lóde òní, ọ̀pọ̀ àwọn ìránṣẹ́ ló ń sá kúrò lọ́dọ̀ ọ̀gá wọn.+