1 Sámúẹ́lì 25:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Kí Ọlọ́run gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá Dáfídì,* kó sì fìyà jẹ wọ́n gan-an tí mo bá jẹ́ kí ìkankan lára àwọn ọkùnrin* rẹ̀ ṣẹ́ kù títí di àárọ̀ ọ̀la.”
22 Kí Ọlọ́run gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá Dáfídì,* kó sì fìyà jẹ wọ́n gan-an tí mo bá jẹ́ kí ìkankan lára àwọn ọkùnrin* rẹ̀ ṣẹ́ kù títí di àárọ̀ ọ̀la.”