1 Sámúẹ́lì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìgbà náà ni Ẹlikénà lọ sí ilé rẹ̀ ní Rámà, àmọ́ ọmọdékùnrin náà di òjíṣẹ́* Jèhófà+ níwájú àlùfáà Élì. 1 Sámúẹ́lì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Sámúẹ́lì sì ń ṣe ìránṣẹ́+ níwájú Jèhófà, ó wọ* éfódì tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọdékùnrin ni.
11 Ìgbà náà ni Ẹlikénà lọ sí ilé rẹ̀ ní Rámà, àmọ́ ọmọdékùnrin náà di òjíṣẹ́* Jèhófà+ níwájú àlùfáà Élì.
18 Sámúẹ́lì sì ń ṣe ìránṣẹ́+ níwájú Jèhófà, ó wọ* éfódì tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọdékùnrin ni.