-
Àwọn Onídàájọ́ 19:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Wọ́n wá ń bá ìrìn àjò wọn lọ, oòrùn sì ti ń wọ̀ nígbà tí wọ́n ń sún mọ́ Gíbíà, tó jẹ́ ti Bẹ́ńjámínì.
-
-
1 Sámúẹ́lì 10:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Sọ́ọ̀lù pẹ̀lú lọ sí ilé rẹ̀ ní Gíbíà, àwọn jagunjagun tí Jèhófà ti fọwọ́ tọ́ ọkàn wọn sì bá a lọ.
-