-
1 Sámúẹ́lì 24:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Torí náà, Sọ́ọ̀lù kó ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ọkùnrin tí ó yàn látinú gbogbo Ísírẹ́lì, ó sì wá Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ lọ sórí àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àpáta tí àwọn ewúrẹ́ orí òkè máa ń wà.
-