-
1 Sámúẹ́lì 24:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó sọ fún àwọn ọkùnrin rẹ̀ pé: “Jèhófà ò ní fẹ́ gbọ́ rárá pé mo ṣe irú nǹkan bẹ́ẹ̀ sí olúwa mi, ẹni àmì òróró Jèhófà, pé mo gbé ọwọ́ mi sókè sí i, torí ẹni àmì òróró Jèhófà ni.”+
-
-
2 Sámúẹ́lì 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìgbà náà ni Dáfídì sọ fún un pé: “Kí ló dé tí ẹ̀rù ò fi bà ọ́ láti gbé ọwọ́ rẹ sókè láti pa ẹni àmì òróró Jèhófà?”+
-
-
1 Kíróníkà 16:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ó ní, ‘Ẹ má fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi,
Ẹ má sì ṣe ohun búburú sí àwọn wòlíì mi.’+
-
-
Sáàmù 20:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Mo ti wá mọ̀ pé Jèhófà ń gba ẹni àmì òróró rẹ̀ sílẹ̀.+
-