ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+

      Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+

      Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,

      Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’

  • 1 Sámúẹ́lì 24:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kí Jèhófà ṣe ìdájọ́ láàárín èmi àti ìwọ,+ kí Jèhófà sì bá mi gbẹ̀san lára rẹ,+ àmọ́ mi ò ní jẹ́ gbé ọwọ́ mi sókè sí ọ.+

  • 1 Sámúẹ́lì 25:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Ní nǹkan bí ọjọ́ mẹ́wàá lẹ́yìn náà, Jèhófà kọ lu Nábálì, ó sì kú.

  • Sáàmù 94:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 94 Jèhófà, Ọlọ́run ẹ̀san,+

      Ìwọ Ọlọ́run ẹ̀san, máa tàn yanran!

  • Sáàmù 94:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Yóò mú kí iṣẹ́ ibi wọn dà lé wọn lórí.+

      Yóò fi iṣẹ́ ibi wọn pa wọ́n run.*

      Jèhófà Ọlọ́run wa yóò pa wọ́n run.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́