-
1 Sámúẹ́lì 18:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Èyí mú kí Sọ́ọ̀lù túbọ̀ máa bẹ̀rù Dáfídì, Sọ́ọ̀lù sì wá di ọ̀tá Dáfídì jálẹ̀ ọjọ́ ayé rẹ̀.+
-
-
1 Sámúẹ́lì 23:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ẹ fara balẹ̀ wá gbogbo ibi tó máa ń fara pa mọ́ sí, kí ẹ sì mú ẹ̀rí bọ̀ wá fún mi. Nígbà náà, màá bá yín lọ, tó bá sì wà ní ilẹ̀ náà, màá wá a jáde láàárín gbogbo ẹgbẹẹgbẹ̀rún* Júdà.”
-