ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 25:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Lójú ẹsẹ̀, Dáfídì sọ fún àwọn ọkùnrin rẹ̀ pé: “Kí kálukú yín sán idà rẹ̀!”+ Nítorí náà, gbogbo wọn sán idà wọn, Dáfídì náà sán idà rẹ̀, nǹkan bí ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọkùnrin sì tẹ̀ lé Dáfídì, nígbà tí igba (200) ọkùnrin jókòó ti ẹrù wọn.

  • 1 Sámúẹ́lì 30:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ní kíá, Dáfídì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin+ tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ gbéra, wọ́n sì lọ títí dé Àfonífojì Bésórì, ibẹ̀ ni àwọn kan lára wọn dúró sí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́