-
1 Sámúẹ́lì 21:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Níkẹyìn, Ákíṣì sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ẹ rí i pé orí ọkùnrin yìí ti yí! Kí ló dé tí ẹ fi mú un wá sọ́dọ̀ mi?
-
-
1 Sámúẹ́lì 27:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí náà, Ákíṣì gba Dáfídì gbọ́, ó sì ń sọ fún ara rẹ̀ pé: ‘Ó dájú pé ó ti di ẹni ìkórìíra láàárín àwọn èèyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì, torí náà, á máa jẹ́ ìránṣẹ́ mi títí lọ.’
-