1 Sámúẹ́lì 25:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Dáfídì ti fẹ́ Áhínóámù+ láti Jésírẹ́lì,+ àwọn obìnrin méjèèjì sì di ìyàwó rẹ̀.+