Ẹ́kísódù 25:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí wọ́n ṣe ibi mímọ́ fún mi, èmi yóò sì máa gbé láàárín* wọn.+ 1 Sámúẹ́lì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọn kò tíì pa fìtílà Ọlọ́run,+ Sámúẹ́lì sì ń sùn nínú tẹ́ńpìlì*+ Jèhófà, níbi tí Àpótí Ọlọ́run wà. 2 Sámúẹ́lì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+
2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+