-
1 Sámúẹ́lì 27:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí náà, Ákíṣì gba Dáfídì gbọ́, ó sì ń sọ fún ara rẹ̀ pé: ‘Ó dájú pé ó ti di ẹni ìkórìíra láàárín àwọn èèyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì, torí náà, á máa jẹ́ ìránṣẹ́ mi títí lọ.’
-
-
1 Sámúẹ́lì 29:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àmọ́ àwọn ìjòyè Filísínì sọ pé: “Kí ni àwọn Hébérù yìí ń wá níbí?” Ákíṣì dá àwọn ìjòyè Filísínì lóhùn pé: “Dáfídì ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù ọba Ísírẹ́lì rèé, ó ti tó ọdún kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ+ tí ó ti wà lọ́dọ̀ mi. Mi ò rí ohun tí kò tọ́ lọ́wọ́ rẹ̀ láti ọjọ́ tí ó ti sá wá sọ́dọ̀ mi títí di òní yìí.”
-