-
1 Sámúẹ́lì 28:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ní kíá, Sọ́ọ̀lù nà gbalaja sórí ilẹ̀, ẹ̀rù sì bà á gan-an nítorí ọ̀rọ̀ “Sámúẹ́lì.” Kò sì sí okun kankan nínú rẹ̀ mọ́, torí pé kò tíì jẹun ní gbogbo ọ̀sán àti ní gbogbo òru.
-