1 Sámúẹ́lì 28:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lákòókò yìí, Sámúẹ́lì ti kú, gbogbo Ísírẹ́lì ti ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ti sin ín sí Rámà ìlú rẹ̀.+ Sọ́ọ̀lù sì ti mú àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́ kúrò ní ilẹ̀ náà.+
3 Lákòókò yìí, Sámúẹ́lì ti kú, gbogbo Ísírẹ́lì ti ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ti sin ín sí Rámà ìlú rẹ̀.+ Sọ́ọ̀lù sì ti mú àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́ kúrò ní ilẹ̀ náà.+