-
1 Sámúẹ́lì 15:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Bí Sámúẹ́lì ṣe ń yíjú pa dà láti lọ, Sọ́ọ̀lù gbá etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀ tí kò lápá mú, aṣọ náà bá fà ya.