1 Sámúẹ́lì 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣùgbọ́n Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ dá Ágágì sí* àti agbo ẹran tó dára jù, títí kan ọ̀wọ́ ẹran, àwọn ẹran àbọ́sanra, àwọn àgbò àti gbogbo ohun tó dára.+ Wọn ò fẹ́ pa wọ́n run. Àmọ́ wọ́n pa gbogbo nǹkan tí kò ní láárí, tí kò sì wúlò run. 1 Kíróníkà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+
9 Ṣùgbọ́n Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ dá Ágágì sí* àti agbo ẹran tó dára jù, títí kan ọ̀wọ́ ẹran, àwọn ẹran àbọ́sanra, àwọn àgbò àti gbogbo ohun tó dára.+ Wọn ò fẹ́ pa wọ́n run. Àmọ́ wọ́n pa gbogbo nǹkan tí kò ní láárí, tí kò sì wúlò run.
13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+