-
1 Sámúẹ́lì 28:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nítorí náà, Sọ́ọ̀lù pa ara dà, ó wọ aṣọ míì, ó sì lọ sọ́dọ̀ obìnrin náà ní òru pẹ̀lú méjì lára àwọn ọkùnrin rẹ̀. Ó ní: “Jọ̀wọ́, bá mi fi agbára ìbẹ́mìílò+ rẹ pe ẹni tí mo bá dárúkọ rẹ̀ fún ọ jáde.”
-