1 Sámúẹ́lì 28:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Dáfídì bá sọ fún Ákíṣì pé: “Ìwọ náà mọ ohun tí ìránṣẹ́ rẹ máa ṣe.” Ni Ákíṣì bá sọ fún Dáfídì pé: “Ìdí nìyẹn tí màá fi yàn ọ́ ṣe ẹ̀ṣọ́ tí á máa ṣọ́ mi nígbà gbogbo.”*+
2 Dáfídì bá sọ fún Ákíṣì pé: “Ìwọ náà mọ ohun tí ìránṣẹ́ rẹ máa ṣe.” Ni Ákíṣì bá sọ fún Dáfídì pé: “Ìdí nìyẹn tí màá fi yàn ọ́ ṣe ẹ̀ṣọ́ tí á máa ṣọ́ mi nígbà gbogbo.”*+