-
1 Sámúẹ́lì 29:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àmọ́ àwọn ìjòyè Filísínì sọ pé: “Kí ni àwọn Hébérù yìí ń wá níbí?” Ákíṣì dá àwọn ìjòyè Filísínì lóhùn pé: “Dáfídì ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù ọba Ísírẹ́lì rèé, ó ti tó ọdún kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ+ tí ó ti wà lọ́dọ̀ mi. Mi ò rí ohun tí kò tọ́ lọ́wọ́ rẹ̀ láti ọjọ́ tí ó ti sá wá sọ́dọ̀ mi títí di òní yìí.”
-
-
1 Sámúẹ́lì 29:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ni Ákíṣì bá dá Dáfídì lóhùn pé: “Lójú tèmi, ìwà rẹ dára bíi ti áńgẹ́lì Ọlọ́run.+ Ṣùgbọ́n àwọn ìjòyè Filísínì ti sọ pé, ‘Má ṣe jẹ́ kí ó bá wa lọ sójú ogun.’
-