1 Sámúẹ́lì 25:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Ìgbà náà ni Ábígẹ́lì+ yára dìde, ó gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, márùn-ún lára àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin sì ń rìn bọ̀ lẹ́yìn rẹ̀; ó bá àwọn òjíṣẹ́ Dáfídì lọ, ó sì di ìyàwó rẹ̀. 1 Sámúẹ́lì 25:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Dáfídì ti fẹ́ Áhínóámù+ láti Jésírẹ́lì,+ àwọn obìnrin méjèèjì sì di ìyàwó rẹ̀.+
42 Ìgbà náà ni Ábígẹ́lì+ yára dìde, ó gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, márùn-ún lára àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin sì ń rìn bọ̀ lẹ́yìn rẹ̀; ó bá àwọn òjíṣẹ́ Dáfídì lọ, ó sì di ìyàwó rẹ̀.