Jóṣúà 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jóṣúà wá súre fún un, ó sì fún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ní Hébúrónì pé kó jẹ́ ogún rẹ̀.+