-
1 Sámúẹ́lì 30:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ dé ìlú náà, wọ́n rí i tí ó ti jó kanlẹ̀, wọ́n sì ti kó àwọn ìyàwó wọn, àwọn ọmọkùnrin wọn pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin wọn lẹ́rú.
-