-
1 Sámúẹ́lì 30:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Dáfídì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọkùnrin ń lé wọn lọ, àmọ́ igba (200) ọkùnrin tí ó ti rẹ̀ débi pé wọn ò lè sọdá Àfonífojì Bésórì dúró síbẹ̀.+
-