-
Jóṣúà 19:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Élítóládì,+ Bẹ́túlì, Hóómà,
-
-
Jóṣúà 19:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 àti gbogbo ìgbèríko tó yí àwọn ìlú yìí ká títí dé Baalati-bíà, ìyẹn Rámà tó wà ní gúúsù. Èyí ni ogún ẹ̀yà Síméónì ní ìdílé-ìdílé.
-