1 Sámúẹ́lì 27:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ákíṣì á béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Ibo ni ẹ ti lọ kó nǹkan lónìí?” Dáfídì á dáhùn pé: “Apá gúúsù* Júdà”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn ọmọ Jéráméélì”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn Kénì”+ ni. 1 Kíróníkà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ọmọ Hésírónì ni Jéráméélì,+ Rámù+ àti Kélúbáì.*
10 Ákíṣì á béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Ibo ni ẹ ti lọ kó nǹkan lónìí?” Dáfídì á dáhùn pé: “Apá gúúsù* Júdà”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn ọmọ Jéráméélì”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn Kénì”+ ni.