Jóṣúà 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jóṣúà wá súre fún un, ó sì fún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ní Hébúrónì pé kó jẹ́ ogún rẹ̀.+ 2 Sámúẹ́lì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ sínú ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Jèhófà sọ fún un pé: “Lọ.” Dáfídì bá béèrè pé: “Ibo ni kí n lọ?” Ó fèsì pé: “Lọ sí Hébúrónì.”+
2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ sínú ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Jèhófà sọ fún un pé: “Lọ.” Dáfídì bá béèrè pé: “Ibo ni kí n lọ?” Ó fèsì pé: “Lọ sí Hébúrónì.”+