1 Kíróníkà 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nérì+ bí Kíṣì; Kíṣì bí Sọ́ọ̀lù;+ Sọ́ọ̀lù bí Jónátánì,+ Maliki-ṣúà,+ Ábínádábù+ àti Eṣibáálì.*+