1 Sámúẹ́lì 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì rí i pé àwọn ti wọ ìjàngbọ̀n, torí pé ọwọ́ ọ̀tá le mọ́ wọn; ni àwọn èèyàn náà bá bẹ̀rẹ̀ sí í fara pa mọ́ sínú ihò àpáta,+ sínú kòtò, sínú pàlàpálá àpáta, ihò* abẹ́lẹ̀ àti àwọn kòtò omi.
6 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì rí i pé àwọn ti wọ ìjàngbọ̀n, torí pé ọwọ́ ọ̀tá le mọ́ wọn; ni àwọn èèyàn náà bá bẹ̀rẹ̀ sí í fara pa mọ́ sínú ihò àpáta,+ sínú kòtò, sínú pàlàpálá àpáta, ihò* abẹ́lẹ̀ àti àwọn kòtò omi.