Àwọn Onídàájọ́ 16:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn alákòóso Filísínì kóra jọ láti rú ẹbọ ńlá sí Dágónì+ ọlọ́run wọn, kí wọ́n sì ṣe àjọyọ̀, torí wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run wa ti fi Sámúsìn ọ̀tá wa lé wa lọ́wọ́!”
23 Àwọn alákòóso Filísínì kóra jọ láti rú ẹbọ ńlá sí Dágónì+ ọlọ́run wọn, kí wọ́n sì ṣe àjọyọ̀, torí wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run wa ti fi Sámúsìn ọ̀tá wa lé wa lọ́wọ́!”