2 Sámúẹ́lì 21:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, Dáfídì lọ kó egungun Sọ́ọ̀lù àti egungun Jónátánì ọmọ rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn aṣáájú* Jabeṣi-gílíádì+ tí wọ́n jí egungun náà kó ní ojúde ìlú Bẹti-ṣánì, níbi tí àwọn Filísínì gbé wọn kọ́ sí ní ọjọ́ tí àwọn Filísínì pa Sọ́ọ̀lù ní Gíbóà.+
12 Torí náà, Dáfídì lọ kó egungun Sọ́ọ̀lù àti egungun Jónátánì ọmọ rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn aṣáájú* Jabeṣi-gílíádì+ tí wọ́n jí egungun náà kó ní ojúde ìlú Bẹti-ṣánì, níbi tí àwọn Filísínì gbé wọn kọ́ sí ní ọjọ́ tí àwọn Filísínì pa Sọ́ọ̀lù ní Gíbóà.+