Sáàmù 55:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ju ẹrù rẹ sọ́dọ̀ Jèhófà,+Yóò sì gbé ọ ró.+ Kò ní jẹ́ kí olódodo ṣubú* láé.+ Sáàmù 65:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ Olùgbọ́ àdúrà, ọ̀dọ̀ rẹ ni onírúurú èèyàn* yóò wá.+