6 Ọ̀dọ́kùnrin náà fèsì pé: “Ó ṣẹlẹ̀ pé mo wà ní orí Òkè Gíbóà,+ ni mo bá rí Sọ́ọ̀lù tó fi ara ti ọ̀kọ̀ rẹ̀, àwọn tó ń gun kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn agẹṣin sì ti ká a mọ́.+
10 Torí náà, mo dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, mo sì pa á,+ nítorí mo mọ̀ pé kò lè yè é lẹ́yìn tí ó ti fara gbọgbẹ́ tí ó sì ti ṣubú. Lẹ́yìn náà, mo ṣí adé* orí rẹ̀, mo sì bọ́ ẹ̀gbà tó wà ní apá rẹ̀, mo sì kó wọn wá fún olúwa mi.”