2 Àwọn Ọba 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Lẹ́yìn náà, Jèhóádà dá májẹ̀mú láàárín Jèhófà àti ọba àti àwọn èèyàn náà,+ pé àwọn á máa jẹ́ èèyàn Jèhófà nìṣó, ó sì tún dá májẹ̀mú láàárín ọba àti àwọn èèyàn náà.+
17 Lẹ́yìn náà, Jèhóádà dá májẹ̀mú láàárín Jèhófà àti ọba àti àwọn èèyàn náà,+ pé àwọn á máa jẹ́ èèyàn Jèhófà nìṣó, ó sì tún dá májẹ̀mú láàárín ọba àti àwọn èèyàn náà.+