-
1 Kíróníkà 11:4-6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Lẹ́yìn náà, Dáfídì àti gbogbo Ísírẹ́lì jáde lọ sí Jerúsálẹ́mù, ìyẹn ní Jébúsì,+ ilẹ̀ tí àwọn ará Jébúsì+ ń gbé. 5 Àwọn tó ń gbé ní Jébúsì pẹ̀gàn Dáfídì pé: “O ò ní wọ ibí yìí!”+ Síbẹ̀, Dáfídì gba ibi ààbò Síónì,+ èyí tó wá di Ìlú Dáfídì.+ 6 Torí náà, Dáfídì sọ pé: “Ẹni tó bá kọ́kọ́ gbéjà ko àwọn ará Jébúsì ló máa di balógun* àti ìjòyè.” Jóábù+ ọmọ Seruáyà ló kọ́kọ́ lọ, ó sì di balógun.
-