ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 14:10-12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Ọlọ́run pé: “Ṣé kí n lọ gbéjà ko àwọn Filísínì? Ṣé wàá fi wọ́n lé mi lọ́wọ́?” Ni Jèhófà bá sọ fún un pé: “Lọ, ó dájú pé màá fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.”+ 11 Torí náà, Dáfídì lọ sí Baali-pérásímù,+ ó sì pa wọ́n níbẹ̀. Dáfídì wá sọ pé: “Ọlọ́run tòótọ́ ti tipasẹ̀ ọwọ́ mi ya lu àwọn ọ̀tá mi, bí ìgbà tí omi bá ya lu nǹkan.” Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pe ibẹ̀ ní Baali-pérásímù.* 12 Àwọn Filísínì fi àwọn ọlọ́run wọn sílẹ̀ níbẹ̀, a sì dáná sun+ wọ́n bí Dáfídì ṣe pa á láṣẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́