-
1 Sámúẹ́lì 18:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jónátánì bọ́ aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tí ó wọ̀, ó sì fún Dáfídì, ó tún fún un ní ìbòrí rẹ̀, idà rẹ̀, ọrun rẹ̀ àti àmùrè rẹ̀ pẹ̀lú.
-
-
1 Sámúẹ́lì 20:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Màá wá ta ọfà mẹ́ta sí apá ibì kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, bíi pé nǹkan kan wà tí mo fẹ́ ta ọfà sí.
-