ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 15:25, 26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Nígbà náà, Dáfídì àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì pẹ̀lú àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún jọ ń rìn lọ tayọ̀tayọ̀+ láti gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà wá láti ilé Obedi-édómù.+ 26 Torí pé Ọlọ́run tòótọ́ ran àwọn ọmọ Léfì tó ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà lọ́wọ́, wọ́n fi akọ ọmọ màlúù méje àti àgbò méje+ rúbọ.

  • Sáàmù 24:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ẹ gbé orí yín sókè, ẹ̀yin ẹnubodè;+

      Ẹ ṣí sílẹ̀,* ẹ̀yin ẹnu ọ̀nà àtijọ́,

      Kí Ọba ológo lè wọlé!+

  • Sáàmù 68:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Wọ́n rí ìkọ́wọ̀ọ́rìn rẹ, Ọlọ́run,

      Ìkọ́wọ̀ọ́rìn Ọlọ́run mi, Ọba mi, sínú ibi mímọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́