Sáàmù 150:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ fun ìwo láti fi yìn ín.+ Ẹ fi ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù yìn ín.+